1. Sam 12:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Njẹ nisisiyi ẹ duro jẹ, ki emi ki o le ba nyin sọ̀rọ niwaju Oluwa niti gbogbo iṣẹ ododo Oluwa, eyi ti on ti ṣe fun nyin ati fun awọn baba nyin.

1. Sam 12

1. Sam 12:3-10