1. Sam 12:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Samueli si wi fun awọn enia na pe, Oluwa li ẹniti o ti yan Mose ati Aaroni, on li ẹni ti o si mu awọn baba nyin goke ti ilẹ Egipti wá.

1. Sam 12

1. Sam 12:5-11