1. Kro 2:4-6 Yorùbá Bibeli (YCE) Tamari aya-ọmọ rẹ̀ si bi Faresi ati Sera fun u. Gbogbo awọn ọmọ Juda jẹ marun. Awọn ọmọ Faresi