1. Kro 3:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

WỌNYI li awọn ọmọ Dafidi, ti a bi fun u ni Hebroni; akọbi Amnoni, lati ọdọ Ahinoamu ara Jesreeli; ekeji Danieli, lati ọdọ Abigaili ara Karmeli;

1. Kro 3

1. Kro 3:1-6