1. Kro 2:35-38 Yorùbá Bibeli (YCE) Ṣeṣani si fi ọmọbinrin rẹ̀ fun Jarha iranṣẹ rẹ̀ li aya; on si bi Attai fun u. Attai si bi Natani