1. Kro 2:14-17 Yorùbá Bibeli (YCE)

14. Netanneeli ẹkẹrin, Raddai ẹkarun,

15. Osemu ẹkẹfa, Dafidi ekeje:

16. Awọn arabinrin wọn ni Seruiah ati Abigaili. Ati awọn ọmọ Seruiah; Abiṣai, ati Joabu, ati Asaeli, mẹta.

17. Abigaili si bi Amasa: baba Amasa si ni Jeteri ara Iṣmeeli.

1. Kro 2