1. Kro 2:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE) WỌNYI ni awọn ọmọ Israeli; Rubeni, Simeoni, Lefi, ati Juda, Issakari, ati Sebuluni, Dani, Josefu, ati Benjamini