1. Kor 3:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori ọgbọ́n aiye yi wèrè ni lọdọ Ọlọrun. Nitori a ti kọ ọ pe, Ẹniti o mu awọn ọlọgbọ́n ninu arekereke wọn.

1. Kor 3

1. Kor 3:11-23