1. Kor 3:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki ẹnikẹni máṣe tàn ara rẹ̀ jẹ. Bi ẹnikẹni ninu nyin laiye yi ba rò pe on gbọ́n, ẹ jẹ ki o di aṣiwere, ki o le ba gbọ́n.

1. Kor 3

1. Kor 3:14-23