1. Kor 2:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn awa ti gbà, kì iṣe ẹmi ti aiye, bikoṣe Ẹmí ti iṣe ti Ọlọrun; ki awa ki o le mọ̀ ohun ti a fifun wa li ọfẹ lati ọdọ Ọlọrun wá.

1. Kor 2

1. Kor 2:6-16