1. Kor 2:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori tani ninu enia ti o mọ̀ ohun enia kan, bikoṣe ẹmí enia ti o wà ninu rẹ̀? bẹ̃ni kò si ẹnikan ti o mọ̀ ohun Ọlọrun, bikoṣe Ẹmí Ọlọrun.

1. Kor 2

1. Kor 2:6-16