1. Kor 15:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nipaṣe eyiti a fi ngbà nyin là pẹlu, bi ẹnyin ba di ọ̀rọ ti mo ti wãsu fun nyin mú ṣinṣin, bikoṣepe ẹnyin ba gbagbọ́ lasan.

1. Kor 15

1. Kor 15:1-7