1. Kor 15:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

NJẸ, ará, emi nsọ ihinrere na di mimọ̀ fun nyin ti mo ti wãsu fun nyin, eyiti ẹnyin pẹlu ti gbà, ninu eyi ti ẹnyin si duro;

1. Kor 15

1. Kor 15:1-9