1. Joh 5:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori eyi ni ifẹ Ọlọrun, pe ki awa ki o pa ofin rẹ̀ mọ́: ofin rẹ̀ kò si nira.

1. Joh 5

1. Joh 5:1-4