1. Joh 4:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ìbẹru kò si ninu ifẹ; ṣugbọn ifẹ ti o pé nlé ibẹru jade: nitoriti ìbẹru ni iyà ninu. Ẹniti o bẹ̀ru kò pé ninu ifẹ.

1. Joh 4

1. Joh 4:14-21