1. Joh 4:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ninu eyi li a mu ifẹ ti o wà ninu wa pé, ki awa ki o le ni igboiya li ọjọ idajọ: nitoripe bi on ti ri, bẹ̃li awa si ri li aiye yi.

1. Joh 4

1. Joh 4:7-21