1. Joh 3:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹnikẹni ti o ba korira arakunrin rẹ̀ apania ni: ẹnyin si mọ̀ pe kò si apania ti o ni ìye ainipẹkun lati mã gbé inu rẹ̀.

1. Joh 3

1. Joh 3:13-23