1. Joh 3:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awa mọ̀ pe awa ti rekọja lati inu ikú sinu ìye, nitoriti awa fẹràn awọn ará. Ẹniti kò ba ni ifẹ o ngbé inu ikú.

1. Joh 3

1. Joh 3:5-20