1. A. Ọba 7:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gbogbo wọnyi jẹ okuta iyebiye gẹgẹ bi iwọn okuta gbigbẹ́, ti a fi ayùn rẹ́ ninu ati lode, ani lati ipilẹ de ibori-oke ile, bẹ̃ si ni lode si apa agbala nla.

1. A. Ọba 7

1. A. Ọba 7:3-17