1. A. Ọba 7:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ile rẹ̀ nibiti o ngbe, ni agbala lẹhin ile titi de ọ̀dẹdẹ, si jẹ iṣẹ kanna. Solomoni si kọ́ ile fun ọmọbinrin Farao, ti o ni li aya, bi iloro yi.

1. A. Ọba 7

1. A. Ọba 7:4-18