1. A. Ọba 6:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ilẹkun yara ãrin mbẹ li apa ọtún ile na: nwọn si fi àtẹgun ti o lọ́ri goke sinu yàra ãrin, ati lati yara ãrin bọ sinu ẹkẹta.

1. A. Ọba 6

1. A. Ọba 6:1-14