1. A. Ọba 6:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ile na, nigbati a nkọ́ ọ, okuta ti a ti gbẹ́ silẹ ki a to mu u wá ibẹ li a fi kọ́ ọ, bẹ̃ni a kò si gburo mataka, tabi ãke, tabi ohun-elo irin kan nigbati a nkọ́ ọ lọwọ.

1. A. Ọba 6

1. A. Ọba 6:4-12