1. A. Ọba 6:28-30 Yorùbá Bibeli (YCE)

28. O si fi wura bò awọn kerubu na.

29. O si yá aworan awọn kerubu lara gbogbo ogiri ile na yikakiri ati ti igi-ọpẹ, ati ti itanna eweko, ninu ati lode.

30. Ilẹ ile na li o fi wura tẹ́ ninu ati lode.

1. A. Ọba 6