1. A. Ọba 7:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

ṢUGBỌN Solomoni fi ọdun mẹtala kọ́ ile on tikararẹ̀, o si pari gbogbo iṣẹ ile rẹ̀.

1. A. Ọba 7

1. A. Ọba 7:1-11