1. A. Ọba 3:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina, fi ọkàn imoye fun iranṣẹ rẹ lati ṣe idajọ awọn enia rẹ, lati mọ̀ iyatọ rere ati buburu; nitori tali o le ṣe idajọ awọn enia rẹ yi ti o pọ̀ to yi?

1. A. Ọba 3

1. A. Ọba 3:5-14