1. A. Ọba 3:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iranṣẹ rẹ si mbẹ lãrin awọn enia rẹ ti iwọ ti yàn, enia pupọ, ti a kò le moye, ti a kò si lè kà fun ọ̀pọlọpọ.

1. A. Ọba 3

1. A. Ọba 3:2-14