1. A. Ọba 2:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati nisisiyi bi Oluwa ti wà, ti o ti fi idi mi mulẹ̀, ti o si mu mi joko lori itẹ́ baba mi, ti o si ti kọ́ ile fun mi, gẹgẹ bi o ti wi, loni ni a o pa Adonijah.

1. A. Ọba 2

1. A. Ọba 2:19-31