1. A. Ọba 2:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Solomoni, ọba si fi Oluwa bura pe, Bayi ni ki Ọlọrun ki o ṣe si mi, ati jubẹ pẹlu, nitori Adonijah sọ̀rọ yi si ẹmi ara rẹ̀.

1. A. Ọba 2

1. A. Ọba 2:16-29