Hos 14:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi o dabi ìri si Israeli: on o tanná bi eweko lili; yio si ta gbòngbo rẹ̀ bi Lebanoni.

Hos 14

Hos 14:4-9