Gẹn 9:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹnikẹni ti o ba ta ẹ̀jẹ enia silẹ, lati ọwọ́ enia li a o si ta ẹ̀jẹ rẹ̀ silẹ: nitoripe li aworan Ọlọrun li o dá enia.

Gẹn 9

Gẹn 9:1-15