Gẹn 9:19-21 Yorùbá Bibeli (YCE)

19. Awọn mẹta wọnyi li ọmọ Noa: lati ọdọ wọn li a gbé ti tàn ká gbogbo aiye.

20. Noa si bẹ̀rẹ si iṣe àgbẹ, o si gbìn ọgbà-àjara:

21. O si mu ninu ọti-waini na, o mu amupara; o si tú ara rẹ̀ si ìhoho ninu agọ́ rẹ̀.

Gẹn 9