Gẹn 8:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Niwọ̀n ìgba ti aiye yio wà, ìgba irugbìn, ati ìgba ikore, ìgba otutu ati oru, ìgba ẹ̃run on òjo, ati ọsán ati oru, ki yio dẹkun.

Gẹn 8

Gẹn 8:21-22