Gẹn 9:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

ỌLỌRUN si sure fun Noa, ati fun awọn ọmọ rẹ̀, o si wi fun wọn pe, Ẹ ma bí si i, ẹ si ma rẹ̀, ki ẹ si kún aiye.

Gẹn 9

Gẹn 9:1-8