Gẹn 6:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn iwọ li emi o ba dá majẹmu mi; iwọ o si wọ̀ inu ọkọ̀ na, iwọ ati awọn ọmọ rẹ, ati aya rẹ, ati awọn aya awọn ọmọ rẹ pẹlu rẹ.

Gẹn 6

Gẹn 6:8-19