Gẹn 6:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati emi, wò o, emi nmu kikun-omi bọ̀ wá si aiye, lati pa gbogbo ohun alãye run, ti o li ẹmi ãye ninu kuro labẹ ọrun; ohun gbogbo ti o wà li aiye ni yio si kú.

Gẹn 6

Gẹn 6:16-22