Gẹn 50:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati ọjọ́ ọ̀fọ rẹ̀ kọja, Josefu sọ fun awọn ara ile Farao pe, Njẹ bi emi ba ri ore-ọfẹ li oju nyin emi bẹ̀ nyin, ẹ wi li eti Farao pe,

Gẹn 50

Gẹn 50:3-6