Gẹn 50:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si kún ogoji ọjọ́ fun u; nitoripe bẹ̃li a ikún ọjọ́ awọn ti a kùn li ọṣẹ: awọn ara Egipti si ṣọ̀fọ rẹ̀ li ãdọrin ọjọ́.

Gẹn 50

Gẹn 50:1-6