Gẹn 50:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati awọn arakunrin Josefu ri pe baba wọn kú tán, nwọn wipe, Bọya Josefu yio korira wa, yio si gbẹsan gbogbo ibi ti a ti ṣe si i lara wa.

Gẹn 50

Gẹn 50:12-23