Gẹn 50:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Josefu si pada wá si Egipti, on ati awọn arakunrin rẹ̀, ati gbogbo awọn ti o bá a goke lọ lati sin baba rẹ̀, lẹhin ti o ti sin baba rẹ̀ tán.

Gẹn 50

Gẹn 50:4-23