Gẹn 48:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹnikan si sọ fun Jakobu, o si wipe, Kiyesi i, Josefu ọmọ rẹ tọ̀ ọ wá: Israeli si gbiyanju, o si joko lori akete.

Gẹn 48

Gẹn 48:1-3