Gẹn 48:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

O SI ṣe lẹhin nkan wọnyi ni ẹnikan wi fun Josefu pe, Kiyesi i, ara baba rẹ kò dá: o si mú awọn ọmọ rẹ̀ mejeji, Manasse ati Efraimu pẹlu rẹ̀.

Gẹn 48

Gẹn 48:1-10