Gẹn 42:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn ẹ mú arakunrin nyin abikẹhin fun mi wá; bẹ̃li a o si mọ̀ ọ̀rọ nyin li otitọ, ẹ ki yio si kú. Nwọn si ṣe bẹ̃.

Gẹn 42

Gẹn 42:17-21