Gẹn 42:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi ẹnyin ba ṣe olõtọ enia, ki a mú ọkan ninu awọn arakunrin nyin dè ni ile túbu nyin: ẹ lọ, ẹ mú ọkà lọ nitori ìyan ile nyin.

Gẹn 42

Gẹn 42:16-24