Gẹn 4:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

ADAMU si mọ̀ Efa aya rẹ̀; o si loyun, o si bí Kaini, o si wipe, Mo ri ọkunrin kan gbà lọwọ OLUWA.

Gẹn 4

Gẹn 4:1-2