Gẹn 3:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̃li o lé ọkunrin na jade; o si fi awọn kerubu ati idà ina dè ìha ìla-õrùn Edeni ti njù kakiri, lati ma ṣọ́ ọ̀na igi ìye na.

Gẹn 3

Gẹn 3:18-24