Gẹn 38:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Judah si ri ọmọbinrin ara Kenaani kan nibẹ̀, orukọ ẹniti ijẹ́ Ṣua; o si mú u, o si wọle tọ̀ ọ.

Gẹn 38

Gẹn 38:1-10