Gẹn 38:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

O SI ṣe li akokò na, ni Judah sọkalẹ lọ kuro lọdọ awọn arakunrin rẹ̀, o si yà sọdọ ara Adullamu kan, orukọ ẹniti ijẹ́ Hira.

Gẹn 38

Gẹn 38:1-2