Gẹn 32:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mo si ní malu, ati kẹtẹkẹtẹ, ati agbo-ẹran, ati iranṣẹkunrin, ati iranṣẹbinrin: mo si ranṣẹ wá wi fun oluwa mi, ki emi ki o le ri ore-ọfẹ li oju rẹ.

Gẹn 32

Gẹn 32:1-10