Gẹn 31:40 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bayi ni mo wà; ongbẹ ngbẹ mi li ọsán, otutù si nmu mi li oru: orun mi si dá kuro li oju mi.

Gẹn 31

Gẹn 31:30-49