Gẹn 31:39 Yorùbá Bibeli (YCE)

Eyiti ẹranko fàya emi kò mú u fun ọ wá; emi li o gbà òfo rẹ̀; li ọwọ́ mi ni iwọ bère rẹ̀, a ba jí i li ọsán, a ba jí i li oru.

Gẹn 31

Gẹn 31:29-48